Up next

Ogunfiditimi Family Abibitumi Kasa Final Presentation

79 Views· 01/15/23
Ọbádélé Kambon
Ọbádélé Kambon
214 Subscribers
214

Ogunfiditimi Family Abibitumi Kasa Final Presentation: Christy Essien-Igbokwe's Seun Rere. After studying Yoruba for 4 months with Abibitumi Kasa, Baba Ogunola got the rest of the family into the act!

Ṣeun Rere by Christy Essien-Igbokwe
Ọmọ mi ṣeun rere tìẹ á dára o,
Ọmọ mi gbọ́ tèmi tìẹ á dára o
Ọmọ mi ṣeun rere tìẹ á dára o,
Ọmọ mi gbọ́ tèmi tìẹ á dára o
Ìyá mi mà ṣeun rere, gbàdúrà fún mi
Baba mi mà ṣeun rere, gbàdúrà fún mi
T'ọ́mọdé bá hùwà burúkú wọ́n á nà ìyá rẹ̀ l'ó kọ́ ọ
T'ọ́mọdé bá hùwà burúkú wọ́n á nà bàbá rẹ̀ l'ó kọ́ ọ
Ìyá mi f'ọ̀nà t'ó dáa hàn mi l'áyé
Baba mi f'ìwà t'ó dáa hàn mi l'áyé
Ayé ti mo wà yìí kò mà yé mi o
Èyí ni Ọlọ́run Kejì mi l'áyé
Ìyá wa ẹ ṣeun rere, baba wa ẹ seun rere
Instrumentals
Ìyá mi mà ṣeun rere, gbàdúrà fún mi
Baba mi mà ṣeun rere, gbàdúrà fún mi
T'ọ́mọdé bá hùwà burúkú wọ́n á nà ìyá rẹ̀ l'ó kọ́ ọ
T'ọ́mọdé bá hùwà burúkú wọ́n á ní bàbá rẹ̀ l'ó kọ́ ọ
Ìyá mi f'ọ̀nà t'ó dáa hàn mi l'áyé
Baba mi f'ìwà t'ó dáa hàn mi l'áyé
Ayé ti mo wà yìí kò mà yé mi o
Èyí ni Ọlọ́run Kejì mi l'áyé
Ìyá wa ẹ ṣeun rere, baba wa ẹ ṣeun rere
Ìyá wa ẹ ṣeun rere, tìwa á dára o

Show more

 0 Comments sort   Sort By


Up next